Éfésù 1:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

èyí tí ó jẹ́ ìdánilójú àsansílẹ̀ ogún wa títí yóò fi di àkókò ìràpadà àwọn tí í ṣe ìní Ọlọ́run sí ìyìn ògo rẹ̀.

Éfésù 1

Éfésù 1:5-18