Deutarónómì 9:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n kí ó dá a yín lójú lónìí pé Olúwa Ọlọ́run yín ni ó ń ṣáájú u yín lọ gẹ́gẹ́ bí iná ajónirun. Yóò jó wọn run, yóò sì tẹ orí wọn ba níwájú yín. Ẹ ó sì lé wọ́n jáde, ẹ ó sì run wọ́n kíákíá, bí Olúwa ti ṣèlérí fún un yín.

Deutarónómì 9

Deutarónómì 9:1-8