Deutarónómì 9:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbà tí mo ṣàkíyèsí, mo rí i pé ẹ ti dẹ́sẹ̀ sí Olúwa Ọlọ́run yín. Ẹ ti ṣe ère òrìṣà ní ìrí ọ̀dọ́ màlúù, fún ara yín. Ẹ ti yípadà kánkán kúrò nínú ọ̀nà tí Olúwa ti pàṣẹ fún un yín.

Deutarónómì 9

Deutarónómì 9:15-21