Deutarónómì 9:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fi mí sílẹ̀, jẹ́ kí n run wọ́n, kí n sì pa orúkọ wọn rẹ́ kúrò lábẹ́ ọ̀run. Èmi yóò sì sọ ọ́ di orílẹ̀ èdè tí ó lágbára tí ó sì pọ̀ jù wọ́n lọ.”

Deutarónómì 9

Deutarónómì 9:5-17