Bí àwọn orílẹ̀ èdè tí Olúwa parun níwájú u yín, bákan náà ni ẹ ó parun, torí pé ẹ kò gbọ́ràn sí Olúwa Ọlọ́run yín lẹ́nu.