Deutarónómì 8:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun ni ó mú un yín la ihà ńlá já, ilẹ̀ tí kò sí omi tí ó sì kún fún òùngbẹ, pẹ̀lú àwọn ejò olóró ńláńlá àti àkéekèe. Ó mú omi jáde fún un yín láti inú àpáta.

Deutarónómì 8

Deutarónómì 8:11-16