Deutarónómì 8:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nígbà tí àwọn agbo màlúù yín àti tí ewúrẹ́ ẹ yín bá pọ̀ sí i tán, tí fàdákà àti wúrà yín sì ń peléke sí i, tí ohun gbogbo tí ẹ ní sì ń pọ̀ sí i,

Deutarónómì 8

Deutarónómì 8:8-19