Deutarónómì 7:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Torí pé ènìyàn mímọ́ ni ẹ jẹ́ sí Olúwa Ọlọ́run yín, Olúwa Ọlọ́run yín ti yàn yín láàrin gbogbo ènìyàn lórílẹ̀ ayé, láti jẹ́ ènìyàn rẹ̀: ohun ìní iyebíye rẹ̀.

Deutarónómì 7

Deutarónómì 7:1-8