Deutarónómì 7:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

torí pé wọ́n á yí àwọn ọmọ yín padà kúrò lẹ́yìn mi, láti jẹ́ kí wọn máa sin òrìṣà, ìbínú Olúwa yóò sì wá sórí yín, yóò sì run yín kíákíá.

Deutarónómì 7

Deutarónómì 7:3-8