Deutarónómì 7:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò fi àwọn ọba wọn lé e yín lọ́wọ́, ẹ̀yin ó sì pa orúkọ wọn rẹ́ lábẹ́ ọ̀run. Kò sí ẹni tí yóò lè dojú ìjà kọ yín títí tí ẹ ó fi pa wọ́n run.

Deutarónómì 7

Deutarónómì 7:17-26