Deutarónómì 6:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ fi kọ́ àwọn ọmọ yín gidigidi. Bí ẹ bá jókòó nínú ilé, ẹ jíròrò nípa wọn, àti nígbà tí ẹ bá ń rìn ní ojú ọ̀nà, bí ẹ bá dùbúlẹ̀ àti nígbà tí ẹ bá dìde.

Deutarónómì 6

Deutarónómì 6:3-12