Deutarónómì 6:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fẹ́ràn Olúwa Ọlọ́run rẹ pẹ̀lú gbogbo àyà rẹ àti gbogbo ọkàn rẹ, àti gbogbo agbára rẹ.

Deutarónómì 6

Deutarónómì 6:1-13