Deutarónómì 6:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lójú wa ni Olúwa tí ṣe iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu: tí ó lágbára tí ó sì ba ni lẹ́rù: lórí Éjíbítì àti Fáráò, àti gbogbo ènìyàn rẹ̀.

Deutarónómì 6

Deutarónómì 6:17-25