Deutarónómì 5:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Torí èyí ẹ sọ́ra láti máa ṣe ohun tí Olúwa Ọlọ́run yín tí pa ní àṣẹ fún un yín; ẹ má ṣe yà sọ́tùn-ún tàbí sósì.

Deutarónómì 5

Deutarónómì 5:26-33