Deutarónómì 4:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Orílẹ̀ èdè wo ló tún le lókìkí láti ní àwọn ìlànà òdodo, àti òfin gẹ́gẹ́ bí àwọn òfin wọ̀nyí tí mo ń gbé kalẹ̀ fún un yín lónìí.

Deutarónómì 4

Deutarónómì 4:4-10