Deutarónómì 4:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ pa àwọn ìlànà àti àṣẹ rẹ̀ mọ́ tí mo ń fún un yín lónìí; kí ó ba à le è yẹ yín, kí ẹ̀yin sì le è pẹ́ ní ilẹ̀ tí Olúwa Ọlọ́run yín fún un yín ní gbogbo ìgbà.

Deutarónómì 4

Deutarónómì 4:30-46