Deutarónómì 4:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Inú Olúwa ru sí mi nítorí yín, ó sì ti búra pé èmi kì yóò la Jọ́dánì kọjá, èmi kì yóò sì wọ ilẹ̀ rere tí Olúwa Ọlọ́run fi fún un yín, ní ìní yín.

Deutarónómì 4

Deutarónómì 4:14-23