Deutarónómì 4:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kí ẹ ma ba à ba ara yín jẹ́ nípa ṣíṣe ère fún ara yín, àní ère lóríṣìíríṣìí yálà èyí tí ó ní ìrísí ọkùnrin tàbí tí obìnrin,

Deutarónómì 4

Deutarónómì 4:7-21