Ọlọ́run ayérayé ni ibi ìsádi rẹ,àti ní ìsàlẹ̀ ni apá ayérayé wà.Yóò lé àwọn ọ̀ta rẹ níwájú rẹ,ó sì wí pé, ‘Ẹ máa párun!’