Deutarónómì 33:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn yóò pe àwọn ènìyàn sórí òkèàti níbẹ̀ wọn yóò rú ẹbọ òdodo,wọn yóò mu nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ òkun,nínú ìṣúra tí ó pamọ́ nínú iyanrìn.”

Deutarónómì 33

Deutarónómì 33:15-23