Deutarónómì 33:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó kọ́ Jákọ́bù ní ìdájọ́ rẹ̀àti Ísírẹ́lì ní òfin rẹ̀.Ó mú tùràrí wá ṣíwájú rẹ̀àti ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ẹbọ sísun sórí i pẹpẹ rẹ̀.

Deutarónómì 33

Deutarónómì 33:2-19