Deutarónómì 32:51 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìdí ni pé ẹ̀yin méjèèjì ṣẹ̀ sí mi láàrin àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ní ibi omi Móríbà Kádésì ní ihà Ṣínì àti nítorí ẹ̀yin kò yà mí sí mímọ́ láàrin àwọn ọmọ Isírẹ́lì.

Deutarónómì 32

Deutarónómì 32:42-52