Deutarónómì 32:49 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Gòkè lọ sí Ábárímù sí òkè Nébò ní Móábù, tí ó kọjú sí Jẹ́ríkò, kí o sì wo ilẹ̀ Kénánì ilẹ̀ tí mo ń fi fún àwọn ọmọ Isírẹ́lì, bí ìní i wọn.

Deutarónómì 32

Deutarónómì 32:47-50