Deutarónómì 32:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Móṣè wà pẹ̀lú u Jóṣúà ọmọ Núnì ó sì sọ gbogbo ọ̀rọ̀ orin yìí sí etí ìgbọ́ àwọn ènìyàn.

Deutarónómì 32

Deutarónómì 32:39-49