Deutarónómì 32:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ti èmi ni láti gbẹ̀san; Èmi yóò san án fún wọnní àkókò tí ẹ̀sẹ̀ wọn yóò yọ;ọjọ́ ìdàmú wọn sún mọ́ etíléohun tí ó sì ń bọ̀ wá bá wọn yára bọ̀.”

Deutarónómì 32

Deutarónómì 32:34-41