Deutarónómì 32:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báwo ni ẹnì kan ṣe lè lé ẹgbẹ̀rún,tàbí tí ẹni méjì sì lè lé ẹgbàaàrún sá,bí kò ṣe pé Àpáta wọn ti tà wọ́n,bí kò ṣe pé Olúwa wọn ti fi wọ́n tọrẹ?

Deutarónómì 32

Deutarónómì 32:22-36