Deutarónómì 32:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jéṣúrúnì sanra tán ó sì tàpá;ìwọ ṣanra tán, ìwọ ki tan, ọ̀rá sì bò ọ́ tán.O kọ Ọlọ́run tí ó dá ọo sì kọ àpáta ìgbàlà rẹ.

Deutarónómì 32

Deutarónómì 32:13-17