Deutarónómì 32:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó mú gun ibi gíga ayéó sì fi èṣo oko bọ́ ọ.Ó sì jẹ́ kí ó mú oyin láti inú àpáta wá,àti òróró láti inú akọ òkúta wá,

Deutarónómì 32

Deutarónómì 32:3-16