Deutarónómì 31:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa yóò sì ṣe fún wọn ohun tí ó ti ṣe sí Ṣíhónì àti sí Ógù ọba Ámórì, tí ó parun pẹ̀lú ilẹ̀ ẹ wọn.

Deutarónómì 31

Deutarónómì 31:3-10