Deutarónómì 31:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Móṣè sì ka ọ̀rọ̀ inú orin yìí láti ìbẹ̀rẹ̀ títí dé òpin sí etí ìgbọ́ ọ gbogbo ìjọ Ísírẹ́lì:

Deutarónómì 31

Deutarónómì 31:21-30