Deutarónómì 31:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ní báyìí kọ ọ́ kalẹ̀ fúnra à rẹ orin yìí kí o sì kọ ọ́ sí Ísírẹ́lì kí o sì jẹ́ kí wọn kọ ọ́ kí ó lè jẹ́ ẹ̀rí ì mi sí wọn.

Deutarónómì 31

Deutarónómì 31:13-29