Deutarónómì 31:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sọ fún Móṣè pé, “Ọjọ́ ikú rẹ ti súnmọ́tílé báyìí. Pe Jóṣúà kí ẹ sì fi ara yín hàn nínú àgọ́ àjọ, níbi tí èmi yóò ti fi àṣẹ fún un.” Nígbà náà ni Móṣè àti Jóṣúà wá, wọ́n sì fara wọn hàn níbi àgọ́ àjọ.

Deutarónómì 31

Deutarónómì 31:8-20