Deutarónómì 30:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ yóò tún gbọ́ràn sí Olúwa àti tẹ̀lé gbogbo àṣẹ rẹ̀ tí mò ń fún ọ lónìí.

Deutarónómì 30

Deutarónómì 30:2-11