Deutarónómì 30:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò mú ọ wá sí ilẹ̀ tí ó jẹ́ ti àwọn baba yín, ìwọ yóò sì mú ìní níbẹ̀. Olúwa yóò mú ọ wà ní àlàáfíà kíkún, yóò mú ọ pọ̀ síi ju àwọn baba yín lọ.

Deutarónómì 30

Deutarónómì 30:1-9