Deutarónómì 3:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo wọn ni a parun pátapáta gẹ́gẹ́ bí á ti ṣe sí Síhónì ọba Hésíbónì, tí a pa gbogbo ìlú wọn run pátapáta: tọkùnrin tobìnrin àti àwọn ọmọ wọn.

Deutarónómì 3

Deutarónómì 3:1-12