Deutarónómì 3:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jáérì ọ̀kan nínú àwọn ìran Mánásè gba gbogbo agbégbé Ágóbù títí dé ààlà àwọn ará Gésúrì àti àwọn ará Mákátì; a sọ ibẹ̀ ní orúkọ rẹ̀ torí èyí ni Básánì fi ń jẹ́ Hafoti-Jáírì títí di òní.)

Deutarónómì 3

Deutarónómì 3:4-15