Deutarónómì 3:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn èyí ní a yípadà tí a sì kọrí sí ọ̀nà tí ó lọ sí Báṣánì, Ógù ọba Báṣánì àti gbogbo jagunjagun rẹ̀ ṣígun wá pàdé wa ní Édíréì.

Deutarónómì 3

Deutarónómì 3:1-9