Deutarónómì 29:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìbínú àti ní ìkannú, àti ní ìrunú ńlá, Olúwa sì fà wọ́n tu kúrò ní ilẹ̀ wọn, ó sì lé wọn lọ sí ilẹ̀ mìíràn, bí ó ti rí ní òní yìí.”

Deutarónómì 29

Deutarónómì 29:24-29