Deutarónómì 29:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Móṣè pàṣẹ fún gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ó sì sọ fún wọn wí pé:Ojú rẹ ti rí gbogbo ohun tí Olúwa ti ṣe ní Éjíbítì sí Fáráò àti, sí gbogbo àwọn ìjòyè e rẹ̀ àti sí ilẹ̀ ẹ rẹ̀.

Deutarónómì 29

Deutarónómì 29:1-3