Deutarónómì 28:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbùkún ni fún ọ nígbà tí Ìwọ bá wọlé, ìbùkún ni fún ọ nígbà tí ìwọ bá jáde.

Deutarónómì 28

Deutarónómì 28:1-13