Deutarónómì 28:58 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ìwọ kò bá rọra tẹ̀lé gbogbo àwọn ọ̀rọ̀ òfin yìí, tí a kọ sínú ìwé yìí, tí ìwọ kò sì bọlá fún ògo yìí àti orúkọ dáradára: orúkọ Olúwa Ọlọ́run rẹ,

Deutarónómì 28

Deutarónómì 28:52-62