Deutarónómì 28:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbùkún ni fún ọmọ inú ù rẹ, àti èṣo ilẹ̀ rẹ, àti irú ohun ọ̀sìn rẹ àti ìbísí i màlúù rẹ àti ọmọ àgùntàn rẹ.

Deutarónómì 28

Deutarónómì 28:1-12