Deutarónómì 28:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa yóò fi ọ́ gégùn ún láti ṣubú níwájú àwọn ọ̀ta rẹ. Ìwọ yóò tọ̀ wọ́n wá ní ọ̀nà kan ṣùgbọ́n ìwọ yóò ṣá fún wọn ní ọ̀nà méje, ìwọ yóò sì padà di ohun ìbẹ̀rù fún gbogbo ìjọba lórí ayé.

Deutarónómì 28

Deutarónómì 28:21-33