Deutarónómì 28:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí o bá gbọ́ràn sí Olúwa Ọlọ́run rẹ ní kíkún kí o sì kíyèsára láti tẹ̀lé gbogbo ohun tí ó pa láṣẹ tí mo fi fún ọ lónìí, Olúwa Ọlọ́run rẹ yóò gbé ọ lékè ju gbogbo orílẹ̀ èdè ayé lọ.

Deutarónómì 28

Deutarónómì 28:1-5