Deutarónómì 26:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

àti pé ní báyìí, mo mú àkọ́so ilẹ̀ tí ìwọ Olúwa ti fún mi wá.” Gbé agbọ̀n náà ṣíwájú Olúwa Ọlọ́run rẹ, kí o sì wólẹ̀ níwájú u rẹ̀.

Deutarónómì 26

Deutarónómì 26:4-19