Deutarónómì 25:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

O gbọdọ̀ ní ìtẹ̀wọ̀n àti òsùwọ̀n pípé àti ti òtítọ́ nítorí náà kí ìwọ kí ó lè pẹ́ ní ilẹ̀ tí Olúwa Ọlọ́run rẹ fún ọ.

Deutarónómì 25

Deutarónómì 25:7-16