Deutarónómì 24:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ọkùnrin kan bá ṣẹ̀ṣẹ̀ gbéyàwó, o kò gbọdọ̀ ran lọ sí ogun tàbí kí ó ní iṣẹ́ kan láti ṣe. Ó ní láti ní òmìnira fún ọdún kan kí ó dúró sílé kí ó sì mú inú dídùn bá ìyàwó rẹ̀ tí ó fẹ́.

Deutarónómì 24

Deutarónómì 24:1-6