Deutarónómì 24:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe yí ìdájọ́ po fún àlejò tàbí aláìní baba, tàbí gba aṣọ ìlékè opó bí ẹ̀rí.

Deutarónómì 24

Deutarónómì 24:12-22