Deutarónómì 24:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe ni alágbàṣe kan lára tí ó jẹ́ talákà àti aláìní, bóyá ó jẹ́ arákùnrin Isírẹ́lì tàbí àlejò tí ó ń gbé ní ọ̀kan nínú àwọn ìlú rẹ.

Deutarónómì 24

Deutarónómì 24:12-20