Deutarónómì 23:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí Ámónì tàbí Móábù tàbí ọ̀kan nínú àwọn ọmọ wọn má ṣe wọ ìpéjọ Olúwa, pàápàá títí dé ìran kẹ̀wàá.

Deutarónómì 23

Deutarónómì 23:1-9